-
Jeremáyà 49:31, 32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “Ẹ dìde, ẹ gòkè lọ láti gbéjà ko orílẹ̀-èdè tó wà lálàáfíà,
Tó ń gbé lábẹ́ ààbò!” ni Jèhófà wí.
“Kò ní ilẹ̀kùn, bẹ́ẹ̀ ni kò ní ọ̀pá ìdábùú; ṣe ni wọ́n ń dá gbé.
32 A ó kó ràkúnmí wọn lọ,
Ohun ọ̀sìn wọn tó pọ̀ rẹpẹtẹ ni a ó sì kó bí ẹrù ogun.
-