Àìsáyà 63:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mo fi ìbínú tẹ àwọn èèyàn mọ́lẹ̀,Mo mú kí wọ́n mu ìrunú mi yó,+Mo sì da ẹ̀jẹ̀ wọn sórí ilẹ̀.” Hábákúkù 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àbùkù ni wọn yóò fi kàn ọ́ dípò ògo. Ìwọ náà mu ún, kí o sì ṣí adọ̀dọ́ rẹ tí wọn ò dá sí gbangba.* Ife ọwọ́ ọ̀tún Jèhófà yóò dé ọ̀dọ̀ rẹ,+Ìtìjú yóò sì bo ògo rẹ mọ́lẹ̀;
16 Àbùkù ni wọn yóò fi kàn ọ́ dípò ògo. Ìwọ náà mu ún, kí o sì ṣí adọ̀dọ́ rẹ tí wọn ò dá sí gbangba.* Ife ọwọ́ ọ̀tún Jèhófà yóò dé ọ̀dọ̀ rẹ,+Ìtìjú yóò sì bo ògo rẹ mọ́lẹ̀;