Jeremáyà 26:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Dúró sí àgbàlá ilé Jèhófà, kí o sì sọ̀rọ̀ fún* gbogbo àwọn ará ìlú Júdà tó wá ń jọ́sìn* ní ilé Jèhófà. Gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ ni kí o sọ fún wọn, má ṣe yọ ọ̀rọ̀ kankan kúrò.
2 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Dúró sí àgbàlá ilé Jèhófà, kí o sì sọ̀rọ̀ fún* gbogbo àwọn ará ìlú Júdà tó wá ń jọ́sìn* ní ilé Jèhófà. Gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ ni kí o sọ fún wọn, má ṣe yọ ọ̀rọ̀ kankan kúrò.