Míkà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí yín,Wọ́n á túlẹ̀ Síónì bíi pápá,Jerúsálẹ́mù á di àwókù,+Òkè Ilé* náà á sì dà bí àwọn ibi gíga nínú igbó.*+
12 Nítorí yín,Wọ́n á túlẹ̀ Síónì bíi pápá,Jerúsálẹ́mù á di àwókù,+Òkè Ilé* náà á sì dà bí àwọn ibi gíga nínú igbó.*+