-
2 Sámúẹ́lì 13:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ìgbà náà ni Támárì da eérú sórí,+ ó fa aṣọ àtàtà tó wọ̀ ya; ó káwọ́ lérí, ó sì bá tirẹ̀ lọ, ó ń sunkún bí ó ṣe ń lọ.