- 
	                        
            
            Jeremáyà 14:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Ni mo bá sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Wò ó, àwọn wòlíì ń sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kò ní rí idà, ìyàn kò sì ní dé bá yín, ṣùgbọ́n Ọlọ́run á fún yín ní àlàáfíà gidi ní ibí yìí.’”+ 
 
-