Jeremáyà 14:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Àsọtẹ́lẹ̀ èké ni àwọn wòlíì náà ń sọ ní orúkọ mi.+ Mi ò rán wọn, bẹ́ẹ̀ ni mi ò pàṣẹ fún wọn, mi ò sì bá wọn sọ̀rọ̀.+ Ìran èké àti ìwoṣẹ́ asán àti ẹ̀tàn ọkàn wọn ni wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀ fún yín.+ Jeremáyà 27:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ àwọn wòlíì tó ń sọ fún yín pé, ‘Ẹ kò ní sin ọba Bábílónì,’+ nítorí èké ni wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀ fún yín.+
14 Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Àsọtẹ́lẹ̀ èké ni àwọn wòlíì náà ń sọ ní orúkọ mi.+ Mi ò rán wọn, bẹ́ẹ̀ ni mi ò pàṣẹ fún wọn, mi ò sì bá wọn sọ̀rọ̀.+ Ìran èké àti ìwoṣẹ́ asán àti ẹ̀tàn ọkàn wọn ni wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀ fún yín.+
14 Ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ àwọn wòlíì tó ń sọ fún yín pé, ‘Ẹ kò ní sin ọba Bábílónì,’+ nítorí èké ni wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀ fún yín.+