Sefanáyà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà ti mú àwọn ìdájọ́ kúrò lórí rẹ.+ Ó ti lé ọ̀tá rẹ dà nù.+ Ọba Ísírẹ́lì, Jèhófà, wà ní àárín rẹ.+ Ìwọ kò ní bẹ̀rù àjálù mọ́.+
15 Jèhófà ti mú àwọn ìdájọ́ kúrò lórí rẹ.+ Ó ti lé ọ̀tá rẹ dà nù.+ Ọba Ísírẹ́lì, Jèhófà, wà ní àárín rẹ.+ Ìwọ kò ní bẹ̀rù àjálù mọ́.+