Àìsáyà 55:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ wá Jèhófà nígbà tí ẹ lè rí i.+ Ẹ pè é nígbà tó wà nítòsí.+