-
Jeremáyà 29:31, 32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “Ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn tó wà ní ìgbèkùn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nípa Ṣemáyà ará Néhélámù nìyí: “Nítorí pé Ṣemáyà ti sọ tẹ́lẹ̀ fún yín, bó tilẹ̀ jẹ́ pé mi ò rán an, tó sì fẹ́ mú kí ẹ gbẹ́kẹ̀ lé irọ́,+ 32 nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wò ó, màá fìyà jẹ Ṣemáyà ará Néhélámù àti àtọmọdọ́mọ rẹ̀. Kò ní sí ọkùnrin kankan tó jẹ́ tirẹ̀ tó máa yè bọ́ lára àwọn èèyàn yìí, kò sì ní rí ohun rere tí màá ṣe fún àwọn èèyàn mi,’ ni Jèhófà wí, ‘nítorí ó ti mú kí wọ́n dìtẹ̀ sí Jèhófà.’”’”
-