2 Àwọn Ọba 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọmọ ọdún mẹ́jọ ni Jòsáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n (31) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jédídà ọmọ Ádáyà láti Bósíkátì.+
22 Ọmọ ọdún mẹ́jọ ni Jòsáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n (31) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jédídà ọmọ Ádáyà láti Bósíkátì.+