Jeremáyà 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nítorí mo gbọ́ ohùn kan tó dà bíi ti obìnrin tó ń ṣàìsàn,Ìdààmú bíi ti obìnrin tó ń rọbí àkọ́bí ọmọ rẹ̀,Ohùn ọmọbìnrin Síónì tó ń mí gúlegúle. Bó ṣe tẹ́ àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, ó ń sọ pé:+ “Mo gbé, àárẹ̀ ti mú mi* nítorí àwọn apààyàn!” Míkà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí ló wá dé tí o fi ń pariwo? Ṣé o kò ní ọba ni,Àbí ẹni tó ń gbà ọ́ nímọ̀ràn ti ṣègbé,Tí ara fi ń ro ọ́, bí obìnrin tó ń rọbí?+
31 Nítorí mo gbọ́ ohùn kan tó dà bíi ti obìnrin tó ń ṣàìsàn,Ìdààmú bíi ti obìnrin tó ń rọbí àkọ́bí ọmọ rẹ̀,Ohùn ọmọbìnrin Síónì tó ń mí gúlegúle. Bó ṣe tẹ́ àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, ó ń sọ pé:+ “Mo gbé, àárẹ̀ ti mú mi* nítorí àwọn apààyàn!”
9 Kí ló wá dé tí o fi ń pariwo? Ṣé o kò ní ọba ni,Àbí ẹni tó ń gbà ọ́ nímọ̀ràn ti ṣègbé,Tí ara fi ń ro ọ́, bí obìnrin tó ń rọbí?+