Àìsáyà 49:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àmọ́ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Kódà, a máa gba àwọn tí alágbára ọkùnrin mú lẹ́rú kúrò lọ́wọ́ rẹ̀,+A sì máa gba àwọn tí ìkà mú sílẹ̀.+ Màá ta ko àwọn alátakò rẹ,+Màá sì gba àwọn ọmọ rẹ là. Jeremáyà 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Ní àkókò yẹn, ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì yóò rìn pa pọ̀,+ wọ́n á sì jọ wá láti ilẹ̀ àríwá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín láti jogún.+
25 Àmọ́ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Kódà, a máa gba àwọn tí alágbára ọkùnrin mú lẹ́rú kúrò lọ́wọ́ rẹ̀,+A sì máa gba àwọn tí ìkà mú sílẹ̀.+ Màá ta ko àwọn alátakò rẹ,+Màá sì gba àwọn ọmọ rẹ là.
18 “Ní àkókò yẹn, ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì yóò rìn pa pọ̀,+ wọ́n á sì jọ wá láti ilẹ̀ àríwá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín láti jogún.+