Àìsáyà 35:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ilẹ̀ tí ooru ti mú kó gbẹ táútáú máa di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,Ilẹ̀ gbígbẹ sì máa di ìsun omi.+ Koríko tútù, esùsú àti òrépètéMáa wà ní ibùgbé tí àwọn ajáko* ti ń sinmi.+ Àìsáyà 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+ Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+
7 Ilẹ̀ tí ooru ti mú kó gbẹ táútáú máa di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,Ilẹ̀ gbígbẹ sì máa di ìsun omi.+ Koríko tútù, esùsú àti òrépètéMáa wà ní ibùgbé tí àwọn ajáko* ti ń sinmi.+
10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+ Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+