Àìsáyà 44:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+ Àìsáyà 48:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+
23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+
20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+