Àìsáyà 58:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà á máa darí rẹ nígbà gbogbo,Ó sì máa tẹ́ ọ* lọ́rùn, kódà ní ilẹ̀ gbígbẹ;+Ó máa mú kí egungun rẹ lágbára,O sì máa dà bí ọgbà tí wọ́n ń bomi rin dáadáa,+Bí ìsun omi, tí omi rẹ̀ kì í tán.
11 Jèhófà á máa darí rẹ nígbà gbogbo,Ó sì máa tẹ́ ọ* lọ́rùn, kódà ní ilẹ̀ gbígbẹ;+Ó máa mú kí egungun rẹ lágbára,O sì máa dà bí ọgbà tí wọ́n ń bomi rin dáadáa,+Bí ìsun omi, tí omi rẹ̀ kì í tán.