Sekaráyà 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Àwọn ọkùnrin àti obìnrin tó ti darúgbó yóò pa dà jókòó ní àwọn ojúde ìlú Jerúsálẹ́mù, kálukú pẹ̀lú ọ̀pá ní ọwọ́ rẹ̀ torí ọjọ́ ogbó wọn.*+
4 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Àwọn ọkùnrin àti obìnrin tó ti darúgbó yóò pa dà jókòó ní àwọn ojúde ìlú Jerúsálẹ́mù, kálukú pẹ̀lú ọ̀pá ní ọwọ́ rẹ̀ torí ọjọ́ ogbó wọn.*+