Ẹ́sírà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọ̀pọ̀ lára àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì pẹ̀lú àwọn olórí agbo ilé, ìyẹn àwọn àgbààgbà tó mọ bí ilé náà ṣe rí tẹ́lẹ̀,+ sunkún kíkankíkan nígbà tí wọ́n rí i tí à ń fi ìpìlẹ̀ ilé yìí lélẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn míì sì ń kígbe ayọ̀ bí ohùn wọn ṣe ròkè tó.+
12 Ọ̀pọ̀ lára àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì pẹ̀lú àwọn olórí agbo ilé, ìyẹn àwọn àgbààgbà tó mọ bí ilé náà ṣe rí tẹ́lẹ̀,+ sunkún kíkankíkan nígbà tí wọ́n rí i tí à ń fi ìpìlẹ̀ ilé yìí lélẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn míì sì ń kígbe ayọ̀ bí ohùn wọn ṣe ròkè tó.+