-
Ìsíkíẹ́lì 18:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Kí ni òwe tí ẹ̀ ń pa ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì yìí túmọ̀ sí, pé, ‘Àwọn bàbá ti jẹ èso àjàrà tí kò pọ́n, àmọ́ àwọn ọmọ ni eyín ń kan’?+
3 “‘Bí mo ti wà láàyè,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘ẹ ò ní pa òwe yìí mọ́ ní Ísírẹ́lì. 4 Wò ó! Gbogbo ọkàn,* tèmi ni wọ́n. Bí ọkàn bàbá ti jẹ́ tèmi, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn ọmọ. Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.
-