Àìsáyà 54:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà máa kọ́ gbogbo àwọn ọmọ* rẹ,+Àlàáfíà àwọn ọmọ* rẹ sì máa pọ̀ gan-an.+ Jòhánù 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èyí túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun,+ pé kí wọ́n wá mọ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo*+ àti Jésù Kristi,+ ẹni tí o rán.
3 Èyí túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun,+ pé kí wọ́n wá mọ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo*+ àti Jésù Kristi,+ ẹni tí o rán.