-
Jóòbù 38:39, 40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Ṣé o lè ṣọdẹ ẹran fún kìnnìún,
Àbí kí o fi oúnjẹ tẹ́ àwọn ọmọ kìnnìún lọ́rùn,+
40 Tí wọ́n bá dùbúlẹ̀ sínú ilé wọn,
Tàbí tí wọ́n lúgọ sínú ibùba wọn?
-
-
Hósíà 5:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Màá dà bí ọmọ kìnnìún sí Éfúrémù
Àti bíi kìnnìún* alágbára sí ilé Júdà.
-