Sáàmù 113:5-7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ta ló dà bíi Jèhófà Ọlọ́run wa,+Ẹni tó ń gbé* ibi gíga? 6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+ 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+
5 Ta ló dà bíi Jèhófà Ọlọ́run wa,+Ẹni tó ń gbé* ibi gíga? 6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+ 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+