Ẹ́sírà 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ ní báyìí, ìwọ Jèhófà Ọlọ́run wa ti ṣojú rere sí wa fún ìgbà díẹ̀, o ti jẹ́ kí àwọn tó ṣẹ́ kù sá àsálà, o sì ti fún wa ní ibi ààbò* nínú ibi mímọ́ rẹ,+ láti mú kí ojú wa máa dán àti láti gbé wa dìde díẹ̀ nínú ipò ẹrú tí a wà, ìwọ Ọlọ́run wa.
8 Àmọ́ ní báyìí, ìwọ Jèhófà Ọlọ́run wa ti ṣojú rere sí wa fún ìgbà díẹ̀, o ti jẹ́ kí àwọn tó ṣẹ́ kù sá àsálà, o sì ti fún wa ní ibi ààbò* nínú ibi mímọ́ rẹ,+ láti mú kí ojú wa máa dán àti láti gbé wa dìde díẹ̀ nínú ipò ẹrú tí a wà, ìwọ Ọlọ́run wa.