Hágáì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní báyìí, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Ẹ kíyè sí* àwọn ohun tí ẹ̀ ń ṣe.