ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:66, 67
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 66 Ẹ̀mí rẹ máa wà nínú ewu ńlá, ẹ̀rù á máa bà ọ́ tọ̀sántòru, kò sì ní dá ọ lójú pé wàá rí ìgbàlà. 67 Ní àárọ̀, wàá sọ pé, ‘Ì bá dáa ká ní alẹ́ la wà!’ tó bá sì di alẹ́, wàá sọ pé, ‘Ì bá dáa ká ní àárọ̀ la wà!’ nítorí ìpayà tó máa bá ọkàn rẹ àti nítorí ohun tí ojú rẹ máa rí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́