Àìsáyà 51:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ohun méjì yìí ti dé bá ọ. Ta ló máa bá ọ kẹ́dùn? Ìparun àti ìsọdahoro, ebi àti idà!+ Ta ló máa tù ọ́ nínú?+ Jeremáyà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ gbé àmì kan dúró* tó ń tọ́ka sí Síónì. Ẹ wá ibi ààbò, ẹ má sì dúró tẹtẹrẹ,”Nítorí mò ń mú àjálù bọ̀ láti àríwá,+ yóò sì jẹ́ ìparun tó bùáyà.
19 Ohun méjì yìí ti dé bá ọ. Ta ló máa bá ọ kẹ́dùn? Ìparun àti ìsọdahoro, ebi àti idà!+ Ta ló máa tù ọ́ nínú?+
6 Ẹ gbé àmì kan dúró* tó ń tọ́ka sí Síónì. Ẹ wá ibi ààbò, ẹ má sì dúró tẹtẹrẹ,”Nítorí mò ń mú àjálù bọ̀ láti àríwá,+ yóò sì jẹ́ ìparun tó bùáyà.