-
Sáàmù 80:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, jọ̀wọ́ pa dà.
Bojú wolẹ̀ láti ọ̀run, kí o sì rí i!
Bójú tó àjàrà yìí,+
-
Sáàmù 102:19-21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ó ń bojú wolẹ̀ láti ibi gíga rẹ̀ mímọ́,+
Láti ọ̀run, Jèhófà ń wo ayé,
20 Kí ó lè gbọ́ bí ẹlẹ́wọ̀n ṣe ń kérora,+
Kí ó lè dá àwọn tí wọ́n ti dájọ́ ikú fún sílẹ̀,+
21 Ká lè kéde orúkọ Jèhófà ní Síónì+
Àti ìyìn rẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù,
-
Àìsáyà 63:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
A ti fà wọ́n sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ mi.
-
-
-
-
-