Jeremáyà 11:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Wò ó, màá pè wọ́n wá jíhìn. Idà ni yóò pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn,+ ìyàn sì ni yóò pa àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin wọn.+
22 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Wò ó, màá pè wọ́n wá jíhìn. Idà ni yóò pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn,+ ìyàn sì ni yóò pa àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin wọn.+