-
1 Àwọn Ọba 6:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ó fi wúrà bo gbogbo ilé náà títí wọ́n fi parí rẹ̀ látòkèdélẹ̀; ó tún fi wúrà bo gbogbo pẹpẹ+ tí ó wà nítòsí yàrá inú lọ́hùn-ún.
-