-
Émọ́sì 6:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Wọ́n ń dùbúlẹ̀ sórí àwọn ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe,+ wọ́n sì ń nà gbalaja sórí àga tìmùtìmù,+
Wọ́n ń jẹ àwọn àgbò inú agbo ẹran àti àwọn ọmọ màlúù* tí wọ́n bọ́ sanra;+
-
Émọ́sì 6:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nítorí náà, àwọn ló máa kọ́kọ́ lọ sí ìgbèkùn,+
Àríyá aláriwo àwọn tó nà gbalaja sì máa dópin.
-
-
-