-
Jeremáyà 26:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nígbà tí Jeremáyà parí gbogbo ohun tí Jèhófà pàṣẹ fún un pé kó sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà, ńṣe ni àwọn àlùfáà àti àwọn wòlíì pẹ̀lú gbogbo àwọn èèyàn náà gbá a mú, wọ́n sì sọ pé: “Ó dájú pé o máa kú.
-
-
Mátíù 23:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Torí náà, ẹ̀ ń jẹ́rìí ta ko ara yín pé ọmọ àwọn tó pa àwọn wòlíì ni yín.+
-