ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 1:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+

      Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,

      Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́!

      Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+

      Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;

      Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i.

  • Àìsáyà 59:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Rárá, àwọn àṣìṣe yín ti pín ẹ̀yin àti Ọlọ́run yín níyà.+

      Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín ti mú kó fi ojú rẹ̀ pa mọ́ fún yín,

      Ó sì kọ̀ láti gbọ́ yín.+

  • Ìsíkíẹ́lì 22:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 ẹ̀jẹ̀ tí o ta sílẹ̀ ti mú kí o jẹ̀bi,+ àwọn òrìṣà ẹ̀gbin rẹ sì ti sọ ọ́ di aláìmọ́.+ O ti mú kí òpin àwọn ọjọ́ rẹ yára sún mọ́lé, àwọn ọdún rẹ sì ti dópin. Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀gàn rẹ, kí gbogbo ilẹ̀ sì fi ọ́ ṣẹlẹ́yà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́