- 
	                        
            
            2 Àwọn Ọba 25:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Àmọ́ àwọn ọmọ ogun Kálídíà lé ọba, wọ́n sì bá a ní aṣálẹ̀ tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹ́ríkò, gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ sì tú ká kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ìdárò 3:52Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        52 Àwọn ọ̀tá mi ti dẹkùn mú mi bí ẹyẹ, láìnídìí. 
 
-