Àìsáyà 39:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 ‘Wọ́n á mú àwọn kan lára àwọn ọmọ tí o máa bí, wọ́n á sì di òṣìṣẹ́ ààfin ní ààfin ọba Bábílónì.’”+ Àìsáyà 43:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí náà, màá sọ àwọn ìjòyè ibi mímọ́ di aláìmọ́,Màá mú kí wọ́n pa Jékọ́bù run,Màá sì mú kí wọ́n sọ̀rọ̀ èébú sí Ísírẹ́lì.+
28 Torí náà, màá sọ àwọn ìjòyè ibi mímọ́ di aláìmọ́,Màá mú kí wọ́n pa Jékọ́bù run,Màá sì mú kí wọ́n sọ̀rọ̀ èébú sí Ísírẹ́lì.+