Sáàmù 74:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run, ìgbà wo ni elénìní máa pẹ̀gàn rẹ dà?+ Ṣé ọ̀tá yóò máa hùwà àìlọ́wọ̀ sí orúkọ rẹ títí láé ni?+ 11 Kí ló dé tí o fi fa ọwọ́ rẹ sẹ́yìn, ọwọ́ ọ̀tún rẹ?+ Nà án jáde láti àyà rẹ,* kí o sì pa wọ́n run.
10 Ọlọ́run, ìgbà wo ni elénìní máa pẹ̀gàn rẹ dà?+ Ṣé ọ̀tá yóò máa hùwà àìlọ́wọ̀ sí orúkọ rẹ títí láé ni?+ 11 Kí ló dé tí o fi fa ọwọ́ rẹ sẹ́yìn, ọwọ́ ọ̀tún rẹ?+ Nà án jáde láti àyà rẹ,* kí o sì pa wọ́n run.