Jeremáyà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ kọ ara yín nílà* fún Jèhófà,Ẹ sì kọlà fún* ọkàn yín,+Ẹ̀yin èèyàn Júdà àti ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerúsálẹ́mù,Kí ìbínú mi má bàa ru jáde bí ináKí ó sì máa jó, tí kò fi ní sí ẹni tó lè pa á,Nítorí ìwà ibi yín.”+
4 Ẹ kọ ara yín nílà* fún Jèhófà,Ẹ sì kọlà fún* ọkàn yín,+Ẹ̀yin èèyàn Júdà àti ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerúsálẹ́mù,Kí ìbínú mi má bàa ru jáde bí ináKí ó sì máa jó, tí kò fi ní sí ẹni tó lè pa á,Nítorí ìwà ibi yín.”+