Sáàmù 74:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọ̀tá rẹ ń bú ramúramù nínú ibi ìpàdé* rẹ.+ Wọ́n fi àwọn ọ̀págun wọn ṣe àmì síbẹ̀.