Ìsíkíẹ́lì 25:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọmọ èèyàn, yíjú sọ́dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì,+ kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí wọn.+ Ìsíkíẹ́lì 25:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Torí ẹ pàtẹ́wọ́,+ tí ẹ fẹsẹ̀ kilẹ̀, tí ẹ* sì ń yọ̀ bí ẹ ṣe ń fi ilẹ̀ Ísírẹ́lì ṣe irú ẹlẹ́yà yìí,+
6 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Torí ẹ pàtẹ́wọ́,+ tí ẹ fẹsẹ̀ kilẹ̀, tí ẹ* sì ń yọ̀ bí ẹ ṣe ń fi ilẹ̀ Ísírẹ́lì ṣe irú ẹlẹ́yà yìí,+