Ọbadáyà 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò yẹ kí o wọ ìlú* àwọn èèyàn mi ní ọjọ́ àjálù wọn,+Kò yẹ kí o fi í ṣe yẹ̀yẹ́ ní ọjọ́ àjálù rẹ̀,Kò sì yẹ kí o fọwọ́ kan ohun ìní rẹ̀ ní ọjọ́ àjálù rẹ̀.+
13 Kò yẹ kí o wọ ìlú* àwọn èèyàn mi ní ọjọ́ àjálù wọn,+Kò yẹ kí o fi í ṣe yẹ̀yẹ́ ní ọjọ́ àjálù rẹ̀,Kò sì yẹ kí o fọwọ́ kan ohun ìní rẹ̀ ní ọjọ́ àjálù rẹ̀.+