2 Àwọn Ọba 23:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jèhófà sọ pé: “Màá mú Júdà kúrò níwájú mi,+ bí mo ṣe mú Ísírẹ́lì kúrò;+ màá kọ Jerúsálẹ́mù sílẹ̀, ìlú tí mo yàn àti ilé tí mo sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Orúkọ mi yóò máa wà níbẹ̀.’”+
27 Jèhófà sọ pé: “Màá mú Júdà kúrò níwájú mi,+ bí mo ṣe mú Ísírẹ́lì kúrò;+ màá kọ Jerúsálẹ́mù sílẹ̀, ìlú tí mo yàn àti ilé tí mo sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Orúkọ mi yóò máa wà níbẹ̀.’”+