- 
	                        
            
            Émọ́sì 8:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Màá sán aṣọ ọ̀fọ̀* mọ́ gbogbo ìbàdí, màá sì mú gbogbo orí pá; Màá ṣe é bí ìgbà téèyàn ń ṣọ̀fọ̀ nítorí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo, Màá sì mú kí ìgbẹ̀yìn rẹ̀ dà bí ọjọ́ tó korò.’ 
 
-