Jeremáyà 9:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí ikú ti gba ojú fèrèsé* wa wọlé;Ó ti wọ àwọn ilé gogoro wa tó láàbòLáti mú àwọn ọmọ kúrò ní àwọn ojú ọ̀nàÀti láti mú àwọn ọ̀dọ́kùnrin kúrò ní àwọn ojúde ìlú.’+ Jeremáyà 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí náà, fi àwọn ọmọ wọn fún ìyàn,Sì fi àwọn fúnra wọn fún idà.+ Kí àwọn ìyàwó wọn ṣòfò ọmọ, kí wọ́n sì di opó.+ Kí àjàkálẹ̀ àrùn pa àwọn ọkùnrin wọn,Kí idà sì pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn lójú ogun.+
21 Nítorí ikú ti gba ojú fèrèsé* wa wọlé;Ó ti wọ àwọn ilé gogoro wa tó láàbòLáti mú àwọn ọmọ kúrò ní àwọn ojú ọ̀nàÀti láti mú àwọn ọ̀dọ́kùnrin kúrò ní àwọn ojúde ìlú.’+
21 Torí náà, fi àwọn ọmọ wọn fún ìyàn,Sì fi àwọn fúnra wọn fún idà.+ Kí àwọn ìyàwó wọn ṣòfò ọmọ, kí wọ́n sì di opó.+ Kí àjàkálẹ̀ àrùn pa àwọn ọkùnrin wọn,Kí idà sì pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn lójú ogun.+