Ìsíkíẹ́lì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Mo wá lọ sọ́dọ̀ àwọn tó wà ní ìgbèkùn ní Tẹli-ábíbù, tí wọ́n ń gbé lẹ́bàá odò Kébárì,+ mo sì dúró síbi tí wọ́n ń gbé; mò ń wò suu,+ mo wà lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ méje.
15 Mo wá lọ sọ́dọ̀ àwọn tó wà ní ìgbèkùn ní Tẹli-ábíbù, tí wọ́n ń gbé lẹ́bàá odò Kébárì,+ mo sì dúró síbi tí wọ́n ń gbé; mò ń wò suu,+ mo wà lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ méje.