-
Ìsíkíẹ́lì 36:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 ‘Mi ò ní mú kí àwọn orílẹ̀-èdè sọ̀rọ̀ èébú sí ọ mọ́, mi ò ní mú kí àwọn èèyàn kẹ́gàn rẹ mọ́,+ o ò sì ní mú àwọn èèyàn rẹ kọsẹ̀ mọ́,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
-