Jẹ́nẹ́sísì 32:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà náà, Jékọ́bù ní kí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kọ́kọ́ lọ sọ́dọ̀ Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ní ilẹ̀ Séírì,+ ní agbègbè* Édómù,+ Diutarónómì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ má ṣe bá wọn fa wàhálà kankan,* torí mi ò ní fún yín ní ìkankan lára ilẹ̀ wọn, bí ò tiẹ̀ ju ìwọ̀n àtẹ́lẹsẹ̀ kan lọ, torí mo ti fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì kó lè di tirẹ̀.+
3 Nígbà náà, Jékọ́bù ní kí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kọ́kọ́ lọ sọ́dọ̀ Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ní ilẹ̀ Séírì,+ ní agbègbè* Édómù,+
5 Ẹ má ṣe bá wọn fa wàhálà kankan,* torí mi ò ní fún yín ní ìkankan lára ilẹ̀ wọn, bí ò tiẹ̀ ju ìwọ̀n àtẹ́lẹsẹ̀ kan lọ, torí mo ti fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì kó lè di tirẹ̀.+