-
Ìsíkíẹ́lì 35:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 “Torí o sọ pé, ‘Orílẹ̀-èdè méjì yìí àti ilẹ̀ méjì yìí yóò di tèmi, méjèèjì á sì di ohun ìní wa,’+ bó tiẹ̀ jẹ́ pé Jèhófà fúnra rẹ̀ wà níbẹ̀,
-