Ọbadáyà 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kò yẹ kí o fi ọmọ ìyá rẹ ṣe yẹ̀yẹ́ ní ọjọ́ tí àjálù bá a,+Kò yẹ kí o yọ̀ lórí àwọn ọmọ Júdà ní ọjọ́ tí wọ́n ń ṣègbé lọ,+Kò sì yẹ kí o máa fọ́nnu ní ọjọ́ wàhálà wọn.
12 Kò yẹ kí o fi ọmọ ìyá rẹ ṣe yẹ̀yẹ́ ní ọjọ́ tí àjálù bá a,+Kò yẹ kí o yọ̀ lórí àwọn ọmọ Júdà ní ọjọ́ tí wọ́n ń ṣègbé lọ,+Kò sì yẹ kí o máa fọ́nnu ní ọjọ́ wàhálà wọn.