Jeremáyà 31:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá sọ àtọmọdọ́mọ* ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà di púpọ̀, tí màá sì sọ àwọn ẹran agbéléjẹ̀ wọn di púpọ̀.”+
27 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá sọ àtọmọdọ́mọ* ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà di púpọ̀, tí màá sì sọ àwọn ẹran agbéléjẹ̀ wọn di púpọ̀.”+