Ìsíkíẹ́lì 23:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Wọ́n ti ṣe àgbèrè,*+ ẹ̀jẹ̀ sì wà lọ́wọ́ wọn. Kì í ṣe pé wọ́n bá àwọn òrìṣà ẹ̀gbin wọn ṣe àgbèrè nìkan ni, wọ́n tún sun àwọn ọmọ tí wọ́n bí fún mi nínú iná kí wọ́n lè di oúnjẹ fún àwọn òrìṣà.+
37 Wọ́n ti ṣe àgbèrè,*+ ẹ̀jẹ̀ sì wà lọ́wọ́ wọn. Kì í ṣe pé wọ́n bá àwọn òrìṣà ẹ̀gbin wọn ṣe àgbèrè nìkan ni, wọ́n tún sun àwọn ọmọ tí wọ́n bí fún mi nínú iná kí wọ́n lè di oúnjẹ fún àwọn òrìṣà.+