Ẹ́kísódù 23:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ̀ẹ̀mẹta lọ́dún ni kí gbogbo ọkùnrin* yín wá síwájú Jèhófà, Olúwa tòótọ́.+